Tope Alabi ft. TY Bello & George – Logan Ti Ode (Lyrics)

Tope Alabi ft. TY Bello & George – Logan Ti Ode

Tope Alabi ft. TY Bello & George – Logan Ti Ode (Lyrics) Mp3 Download

Tope Alabi ft. TY Bello & George – Logan Ti Ode (Lyrics) Mp3, Download Tope Alabi ft. TY Bello & George – Logan Ti Ode (Lyrics) Mp3, Mp4 Video & Zip.

Tope Alabi ft. TY Bello & George – Logan Ti Ode (Lyrics): Enjoy Tope Alabi recent so g “Logan Ti Ode” lyrics, featuring TY Bello & George below;

DOWNLOAD / STREAM AUDIO HERE

(Verse)
Emi mo oun oju mi tiri, mo mo oun eti mi ti gbo
Mo oun oju mi tiri, mo mo oun eti mi ti gbo
Logan to gbo iro Ayo re o Olugbala, aye mi le to
Logan to gbo iro Ayo re o Olugbala, aye mi le to

Mo mo oun aye ma ti wi, mo mo oun eyan ma ti so
Won ti pe wa ni agan ri, boya won ti pewa lo’olosi ri
Sugbon, logan ti o de o Olugbala, aye mi le to
Logan ti o de o Olugbala, aye e le to

Aye to ti daru tele tele o, logan ti o de
Oro ti eniyan ti fi s’alufani re, logan ti o de
Oro ti ko dara ta ti so si o, logan ti o de
Oruko ti kin se tire ta ti pe o, logan ti o de
Ani logan ti o de o Olugbala, aye e le to
Logan ti o de o Olugbala, aye e le to
Logan ti Jesu de o Olugbala, l’aye e le to

Ko s’oruko t’aye o le pe ni, wa ma peni l’agan l’ona gbo gbo
Bo ba lowo lowo agan ni, bo ba bi mo o agan ni
Bo ba tegba ko dagba agan lo je, sugbon logan ti o de, sope logan ti o de
Ani logan ti o de, lesekese, logan ti o de
Ahah, logan ti o de o Olugbala, l’aye e le to
Logan ti o de o Olugbala, l’aye e le to

Instantly lo’n je be, bo se n debe, won de yi oruko pada

Logan ti o de, eheheh logan ti o de, eyin ta pe l’agan e ma so wi pe, logan ti o de
Awon ta ti fi oruko aburu pe ni’le won yi, logan ti o de
Ahah, logan ti o de o Olugbala, l’aye mi le to
Logan ti o de o Olugbala, l’aye mi le to
Ani eheh, logan ti o de o Olugbala, l’aye mi le to
Ani, logan ti o de o aseda, l’aye mi le to
Ani, logan ti o de o Olorun o, l’aye mi le to
Irawo owuro omo Marry yo sinu oro mi, l’aye mi le to
Ah, alagbara ni Shiloh loba ran ti mi si rere, l’aye mi le to
Enu mi wa kun fu eri o gbogbo, l’aye mi le to
Aye mi gba iyipada otun o logan to de, , l’aye mi le to
Aye mi ba leto l’ota ba wo Iran mi, l’aye mi le to
Aye mi le to lo ta bawo Iran mi, l’aye mi le to
Ota kaworo, enu won gbe tan lori oju kan, l’aye mi le to
Ahah, logan ti o de o Olugbala, l’aye mi le to

(Outro)
Thank you Lord Jesus for all that you are..

About Temmyguru 10801 Articles
TemmyGuru is a Blogger, Bitcoin (BTC) exchanger, Physicist, Digital marketer, Promoter, Artiste Manager, Entrepreneur, and Philanthropist. If you have any suggestion, complaint, or Advert. Feel free to contact him. Whatsapp: +2347040694785 Call Only: +2347040694785

Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.
This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.